(“Thou art all fair, my love; there is no spot in thee.” (S. O. S 4:7))
Composer’s Foreword: I am not good in notes, but from the local church trainings while in choir, I have come around with this hymn using another hymn. If you know the hymn beneath, then you can join me to sing this song unto the Lord.
The Tune of Hymn to Use
“How sweet the name of Jesus sounds
Blessed be the name of the Lord
It soothes my sorrows heals my wounds
Blessed be the name of the Lord
Chorus:
Blessed be the name, Blessed be the name
Blessed be the name of the Lord
Blessed be the name, Blessed be the name
Blessed be the name of the Lord
The Composed Song
1. As flow’r of lily even among thorns
That’s how you my beloved is
In the midst of all people in the world
My lover is incomparable
Chorus
Thou use song of love, thou use song of love
Thou use song of love to compass me
Thou use song of love, thou use song of love
Thou use song of love to compass me
2. Beloved’s lips are as thread of scarlet
And her speech is very comely
Her temples are like piece of pomegranate
My lover is incomparable
Chorus
3. Beloved’s eyes are like that of a dove
Her hair is also very long
Her teeth are white like that of the crystals
My lover is incomparable
Chorus
4. Neck of my lover is like a tower
That is built for the armory
Her body resembles that of neonate
My lover is incomparable
Chorus
5. Thou art all fair even thou my beloved
There is no spot on thy body
Thou art on the pinnacle of my heart
My lover is incomparable
Chorus
Orin Kan: Olufẹ Mi Ko Lafiwe
(“Ìwọ li ẹwa gbogbo, olufẹ mi; ko si abawọn lara rẹ” (Orin Sol 4:7))
Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi:
N go mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.
Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi
“B’orukọ Jesu ti dun to
Ogo ni fun orukọ Rẹ
O tan banujẹ at’ ọgbẹ
Ogo ni fun orukọ Rẹ
Ègbè
Ogo f’ okọ Rẹ, Ogo f’ okọ Rẹ
Ogo f’ orukọ Oluwa
Ogo f’ okọ Rẹ, Ogo f’ okọ Rẹ
Ogo f’ orukọ Oluwa
Orin Titun na Nìyí
1. Bi ‘tanna lili ni arin ẹgun
Bẹni ‘wọ Olufẹ mi ri
Larin gbogb’ enia inu aiye
Olufẹ mi ko lafiwe
Ègbè
‘Wọ f’orin ifẹ, ‘Wọ f’orin ifẹ,
‘Wọ f’orin ifẹ,yimika
‘Wọ f’orin ifẹ, ‘Wọ f’orin ifẹ,
‘Wọ f’orin ifẹ,yimika
2. Ètè olufẹ dab’ owu ododo
Bẹ lohun rẹ si dun jọjọ
Ẹrẹkẹ rẹ b’ẹla pomegranate
Olufẹ mi ko lafiwe
Ègbè
3. Oju Olufẹ dabi t’adaba
Irun rẹ si gun pupọ
Ehin rẹ funfun bi ti kristali
Olufẹ mi ko lafiwe
Ègbè
4. Ọrun olufẹ dabi ‘le isọ
Eyit’a kọ fun isura
Ara rẹ bi ti ọmọ jojolo
Olufẹ mi ko lafiwe
Ègbè
5. ‘Wọ l’ẹwa gbogbo ‘wọ olufẹ mi
Ko si abawọn lara rẹ
‘Wọ wa lori sonso ori ọkan mi
Olufẹ mi ko lafiwe
Ègbè
Comments