top of page
Blog: Blog2
Search
olusegundare

Composed Hymn: Blessed One

Author’s (Composer’s) Note: I do not know the conventional musical notes, I would have inscribed it on this to enhance believers’ musical sense and smooth rendition of the song, albeit, I have fashioned the song in tune with one of the worldwide known hymn. If anyone knows the hymns used, such a one can sing this song anywhere in the world.

The tune which this song has been fashioned along or the tune of the hymn that can be used to sing this song is:


Stand Aloof

Ni èdè YorùbáOrin inu iwe ti a le lò niyi,

“Wa s’ọdọ Jesu mase duro

L’ọrọ rẹ l’oti fọna han wa

O duro li arin wa loni

O nwi pẹlẹ pe wa

Ègbè:

Ipade wa yio jẹ ayọ

Gb’ọkan wa ba bọ lọwọ ẹsẹ

T’a o si wa pẹlu rẹ, Jesu,

N’ile ayeraiye”

Akọle Orin na niyi: Alábùkún Fún

1. Ibukun ni fun Ọkọnrin na

Ti ko rin nimọ ẹni ibi

Ti ko duro lọna ẹlẹsẹ

To takete si wọn

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji

Ta si ti bo ẹsẹ rẹ mọlẹ

Ẹni na ta o k’ẹsẹ si lọrun

Alabukun ni fun


Sand Covered the Body, Showing Our Sins Covered

2. Ibukun ni f’awọn ẹniti

On gb’ọrọ awọn alaini ro

‘Tori Oluwa yio gba oun na

Lakoko ipọnju

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji


3. Ẹnikẹni to bẹru Oluwa

“Tinu rẹ si dun si ofin rẹ

Ẹni ibukun lawọn ẹni na

Niwaju Oluwa

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji


Delighted

4. Awọn ẹnit’ope lọna na

Ti nwọn si nrin n’ofin Oluwa

Ti bujoko wọn jinna s’ẹlẹgan

Alabukun ni wọn

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji


5. ‘Bukun ni fun gbogbo ẹniti

Oluwa bawi to tọ sọna

‘Torina mase gan ‘bawi rẹ

Ko le dẹni bukun

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji


Lord's Presence

6. Ọgbọn se iyebiye gidi

J’ohunkohun to mbẹ laiye lọ

Ibukun ni f’ẹni to wari

To si di mu sinsin

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji


7. Awọn to gbẹkẹ wọn l’Oluwa

To f’Oluwa se apata wọn

Ẹni ayọ la o ma pe wọn

At’alabukun fun

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji


8. Talo le r’olotọ enia

To nrin ninu-wa otitọ rẹ

Ibukun ni f’awọn ẹni na

At’iru ọmọ wọn

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji


9. Ibukun ni f’awọn ẹniti

o fi ile rẹ se ibugbe

Ipa ẹnito mbẹ ninu rẹ

nwọn nfiyin wọn fun Ọ

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji


10. Biwọ ba le feti s’ọrọ rẹ

To si nsọna rẹ lojojumọ

To si rọmọ opo ọrọ rẹ

Ẹni ‘bukun ni ọ”

Ègbè:

‘Bukun ni f’ẹni ta dariji


Chairs/Seats

Translation

The hymn’s tune to use for this composed song is beneath

“Come to the Savior make no delay

Here in His word he has shown us the way

Here in our midst he’s standing today

‘Tenderly saying come

Chorus:

Joyful, joyful will the meeting be

When from sin our hearts are pure and free

And we shall gather, savior with thee

In our eternal home”

Composed Song’s Title: Blessed One

1. Blessed be unto that very man

That walks not in ungodly counsel

That do not stand in way of sinners

That stand aloof from them

Chorus:

Blessed is for the one forgiven

The one whose sins have been covered up

On whom sin has not been imputed

He is a blessed one


Undefiled

2. Blessed be unto those people who

Consider plight of ‘em who are poor

For he will also be delivered

In the time of trouble

Chorus:

Blessed is for the one forgiven


3. Whomsoever that feareth the Lord

Who’s also delighted in his law

Those type of people are blessed ones

In the Lord’s presence

Chorus:

Blessed is for the one forgiven


4. Those who are undefiled in the way

And those who walk in law of the Lord

Those whose seats are far from the scornful

They are a blessed one

Chorus:

Blessed is for the one forgiven


Scourging

5. Blessed be unto everyone whom

The Lord correcteth and he scourgeth

Therefore don’t despise his chastisement

To be a blessed one

Chorus:

Blessed is for the one forgiven


6. Very precious is wisdom indeed

Above every other thing in the world

Blessed is that person who finds it

And holds it very firm

Chorus:

Blessed is for the one forgiven


Church

7. Those who repose their trust in the Lord

Those who have made their Lord their Rock

They shall be called the people of joy

And a blessed one

Chorus:

Blessed is for the one forgiven


8. Who is it that can find a just man

Who’s walking in his integrity

Blessed be ‘to those kinds of people

And their children after them

Chorus:

Blessed is for the one forgiven


9. Blessed be unto the kind of people

Who have make your house their dwelling place

The strength of the man who in in you

They ‘r giving you their praise

Chorus:

Blessed is for the one forgiven


Pillars

10. If thou can hearken unto his word

And you are watching it everyday

And you hold ‘to the pillar of his word

You are a blessed one

Chorus:

Blessed is for the one forgiven

2 views0 comments

Recent Posts

See All

HIS PLEA

Comments


bottom of page