Author’s (Composer’s) Note: I do not know the conventional musical notes, I would have inscribed it on this to enhance believers’ musical sense and smooth rendition of the song, albeit, I have fashioned the song in tune with one of the worldwide known hymn. If anyone knows the hymns used, such a one can sing this song anywhere in the world.
The tune which this song has been fashioned along or the tune of the hymn that can be used to sing this song is:
Ni èdè Yorùbá Orin inu iwe ti a le lò ohun rẹ niyi,
“Mo faiye at’ifẹ mi fun,
Ọd’agutan t’o ku fun mi
Jẹ ki nle jẹ olotitọ
Jesu Ọlọrun mi
Ègbè:
Un o wa f’ẹni t’oku fun mi
Aye mi yo si dun pupọ
Un op wa fẹni t’oku fun mi
Jesu Ọlọrun mi”
Orin na niyi: Jehofa Alagbara
1. Oluwa Ẹlẹda Ọrun
Aiye at’ohun to mbẹ ‘nu rẹ
Ọba titi aiyeraiye
Nikan logo yẹ fun
Ègbè:
Iyin at’ọla ni fun ẹni
To tẹ aiye sori omi
To gbọrun ro laisi ọwọn
Jehof’Alagbara
2. Awọn ọrun nsọ t’ogo rẹ
Ofurufu nfisẹ rẹ han
Ọjọ d’ọjọ na ko le dẹkun
Sisọ b’ose tobi to
Ègbè:
Iyin at’ọla ni fun ẹni…
3. Ko sẹni to mọ orison
T’afẹfẹ ti nfẹ jade wa
Tabi ibiti o nfẹ lọ
Bikose ‘wọ Oluwa
Ègbè:
Iyin at’ọla ni fun ẹni…
4. Awọn ‘rawọ to mbẹ l’ọrun
Orun, osupa at’ohun gbogbo
P’arawọnpọ lati ma fi
Ogo fun Ẹlẹda
Ègbè:
Iyin at’ọla ni fun ẹni…
5. O yẹ k’awa ọmọ Ọlọrun
darapọ mọ awọn t’ọrun
Lati fi ohun ‘ni wa gbogbo
yin Oluwa Ọba
Ègbè:
Iyin at’ọla ni fun ẹni…
6. ‘Wọn agba mẹrinlelogun
Wolẹ niwaju Ẹni na
Ti o joko lori itẹ
Jesu Ọba ’wọn ọba
Ègbè:
Iyin at’ọla ni fun ẹni…
7. Emi na p’ẹlawọn t’ọrun
Mo tẹriba mo si wolẹ
Niwaju rẹ Ọd’agutan
To k’ẹsẹ aiye lọ
Ègbè:
Iyin at’ọla ni fun ẹni…
Translation
The tune to use for the composed Hymn is the Hymn beneath:
“My life, my love, I give to Thee
Thou Lamb of God who died for me,
Oh may I ever faithful be,
My saviour and my God
Chorus:
I ‘ll live for him who died for me
How happy then my life shall be!
I ‘ll live for him who died for me
My saviour and my God!”
The Composed Hymn’s Title: Jehovah The Mighty
1. Lord, creator of the heaven
Earth and the things that is therein
The everlasting king alone
Is worthy of glory
Chorus:
Glory ‘n’ honor be unto him
That spread the earth on the water
Who hold heaven without pillar
Jehovah the Mighty
2. The heavens declare thine glory
The firmament reveal your works
Day unto day also can’t cease
To talk of how great you are
Chorus:
Glory ‘n’ honor be unto him…
3. There is no one that knows the source
That the wind used to blow out from
Neither where the wind’s blowing to
Exceptin’ you oh Lord
Chorus:
Glory ‘n’ honor be unto him…
4. Those stars present in the firmament
The sun, the moon, including all
Come together to come and give
Glory to the creator
Chorus:
Glory ‘n’ honor be unto him…
5. It meets that the children of God
Join with them who are in heaven
To use all of their properties
To praise the Lord the King
Chorus:
Glory ‘n’ honor be unto him…
6. The four and the twenty elders
They fell down before the Person
Who is sitting upon the throne
Jesus the King of kings
Chorus:
Glory ‘n’ honor be unto him…
7. I join those who are in heaven
To bow to earth and to fall down
Before the presence of the Lamb
That takes world sins away
Chorus:
Glory ‘n’ honor be unto him…
Comments