top of page
Blog: Blog2
Search
olusegundare

Composed Hymn: Put Your Trust In Him

Author’s (Composer’s) Note: I do not know the conventional musical notes, I would have inscribed it on this to enhance believers’ musical sense and smooth rendition of the song, albeit, I have fashioned the song in tune with one of the worldwide known hymn. If anyone knows the hymns used, such a one can sing this song anywhere in the world.

The tune which this song has been fashioned along or the tune of the hymn that can be used to sing this song is:


Chariot and Horse


Ni èdè Yorùbá Orin inu iwe ti a le lò niyi, “Ọba Ogo Alafia ngo fẹran Rẹ...”

Akọle Orin na niyi: Fi Ìgbẹkẹle rẹ Sinu Rẹ

1. Sa gbẹkẹle Oluwa

Ẹlẹda Rẹ

O-un nikan ni o yẹ

Lat’gbẹkẹle

‘Tori Oun nikan ni

Ki doju tini

Ẹlẹda Aiyeraiye

Oluwa Ogo


2. Awọn miran gbẹkẹle

Kẹkẹ at’ ẹsin

Sugbọn ohun ta o ranti ni

Orukọ Rẹ nla

Ohun to sọ ‘nu ọrọ rẹ ni pe

Ẹ ke pe mi

Nigbakugba tẹba pe

Em’o dahun


3. Iwọ yio ma pawọn mọ

L’alafia pipe

Awọn to ba gbẹkẹ wọn

Le ‘wọ nikan

Nin’ aiye aisi sinmi yi

Yio ri isinmi

Nitori wọn fi gbagbọ

Wọn sinu Rẹ


Rescuer

4. Koda baba ati iya

Le kọ ẹ silẹ

Sugbọn Ọlọrun Israẹli

Ki kọni silẹ

Ko kọ awọn igbani

‘Nu isoro wọn

‘Tori na ki yio kọ ẹ

Bo gbẹkẹle


5. ‘Wọ Ọlọrun mi nikan

Ni mo gbẹkẹle

Mase jẹ koju timi

Mo mbẹ ọ Ò

Ero ọta mi ni pe

Awọn yio bori

Sugbọn iwọ mase gba

K’wọn bor’ọkan mi


6. Mo ti gbẹkẹmi le Ọ

‘Wọ Oluwa mi

‘Torina ‘wọ k’yio jẹ ki

Ẹsẹ mi yẹ

‘Tori o mọ irin mi

O ti wadi mi

‘Wọ si ti mọ daju pe

Mo gbẹkẹle Ẹ


7. Awọn 7.k o gbẹkẹ wọn

L’Oluwa Ọlọrun

Sugbọn ti wọn gbẹkẹ wọn

L’agbara wọn

La o fa tu kuro ni

Orilẹ aiye

Olododo yio ri

Yio si rẹrin


Laughing Baby

8. Iwọ ni agbara mi

At’apata mi

Iwọ tun ni ‘gbala mi

At’asa mi

Iwọ nilu olodi mi

‘Le-isọ giga mi

Ran mi lọwọ Oluwa

Lati gbẹkẹ le Ọ


My Rock

Translation

The tune to use for this song is this:

“King of glory, king of Peace,

I will love Thee

And that love may never cease,

I will move thee

Thou hast granted my request

Thou hast heard me,

Thou didst note my working breast

Thou hast spared me”


The Hymn: Put Your Trust in Him


1. Just put your trust in the Lord

Thine creator

Its him alone that’s worthy

To put trust in

Because it is him alone

That don’t put to shame

Everlasting deliverer

Lord of glory.


2. Some people put their trust in

Chariots an’ horses

But what we ‘ll remember is

Your name that’s great

What you say in Thine Word is

You should call on me,

Whensoever you call me

I ‘ll answer you


My Fortress

3. You will keep on keeping him

In perfect peace

And all who can put their trust

In only thee

In this world of restlessness

They ‘l find your rest

Because they have put their faith

In only you


4. Even your father and mother

May forsake you

But the God of the Israel

Will never forsake

He forsake not the ancients

When they ‘r in difficulty

Therefore he wont forsake you

If you trust him


Father and Mother Walking...You may be forsaken

5. My God it is you alone

That I trust in

Let me not be put to shame

I beseech thee

The enemies thought is that

They ‘ll triumph over me

But you should not allow them

Overcome my soul


6. I have put my trust in you

You who ‘r my Lord

Therefore you ‘ll never allow

My feet to slip

Because thou hast known my walk

You ‘ve examine me

And you assuredly know that

I trust in you


7. Those who do not put their trust

On the Lord God

But who have their trust reposed

On their power alone

‘ll be uprooted off from

Surface of the earth

Righteous people shall see this

And they will laugh


My Buckler

8. Thou oh Lord art my power

And thou art my rock

Also you ‘r my salvation

And you ‘ r my buckler

You are my fortress city

And my high tower

I am asking for thy help

To trust in you

2 views0 comments

Recent Posts

See All

HIS PLEA

Comments


bottom of page